Sunday, 8 October 2017

LYRICS: dj consequences - Assignment ft. Olamide (Prod. young John)

dj consequences ft olamide - Assignment

[INTRO]
Gbo
Say baddo
Wherever you see young John say babo
Ayoyoyo say baddo
Wherever you see consequence say babo

[CHORUS]
Tí kò bá ní di obìnrin òní jẹ́ kumolu
Wọn là wá gbé bagi bí alajọ́ somolu
Tí ń bá gbowó ni sìn wọ́n á ní mo ṣe yahoo
Ti n ba wọ private jet wọ́n a tuni ní mo ga hu
Wọn wa di ẹ
Assignment
Wọn wa di ẹ
Assignment
Ó wọ kini yẹn
Assignment
Wọn wa di ẹ
Assignment
[VERSE]
Slay queen mà pami now
Baby take palmy now
Or you like ribbina
Wo na you sabi now
Tinted dogolodo
Fitted gborogodo
Yaro dogo dogo
Na person farm okoloko
Na kokunfoundation
Fowó ṣe charity
ta lo ń jẹ charity
Ẹjọ́ ẹ bá wà wa charity
Slay queen yi ti para
Na money be mora
Klse ka a lora
Ibadi ni jo wa

[SUB-CHORUS]
Ṣe shomolu wa
Yes kẹ̀
Ó loyo pomo
Yes kẹ́
Epetedo unkọ́
Yes kẹ́
Àwọn tí Ambode
Yes kẹ́
Mushinolosha da
Yes kẹ́
Wọn timba sì bẹ
Yes kẹ́
Ẹ́ ma ṣe wéré ni bodilo
Yes kẹ́
ibe lọgawa
Yes kẹ́
Okat

[CHORUS]


Tí kò bá ní di obìnrin òní jẹ́ kumolu
Wọn là wá gbé bagi bí alajọ́ somolu
Tí ń bá gbowó ni sìn wọ́n á ní mo ṣe yahoo
Ti n ba wọ private jet wọ́n a tuni ní mo ga hu
Wọn wa di ẹ
Assignment
Wọn wa di ẹ
Assignment
Ó wọ kini yẹn
Assignment
Wọn wa di ẹ
Assignment


[VERSE]

Like paso i wonda
Please i am not your brother
Mommy you are not my mother
ma she were pass my border
My money my cheda
Owun tún da eda pada
Na baba be father
Who tell you pomo na leather
King like Gucci gucci
Peru Gucci Gucci
Fela Kuti kuti
Isẹ yẹn rọ́ sushi sushi
Mr. Preacher preacher fẹ́ mọ n kan to pa iya teacher
Who can fi shak fi shak
Kọ́n fi were sì nù shisha


[SUB-CHORUS]
Ṣe shomolu wa
Yes kẹ̀
Ó loyo pomo
Yes kẹ́
Epetedo unkọ́
Yes kẹ́
Àwọn tí Ambode
Yes kẹ́
Mushinolosha da
Yes kẹ́
Wọn timba sì bẹ
Yes kẹ́
Ẹ́ ma ṣe wéré ni bodilo
Yes kẹ́
ibe lọgawa
Yes kẹ́
Okat

[CHORUS]

Tí kò bá ní di obìnrin òní jẹ́ kumolu
Wọn là wá gbé bagi bí alajọ́ somolu
Tí ń bá gbowó ni sìn wọ́n á ní mo ṣe yahoo
Ti n ba wọ private jet wọ́n a tuni ní mo ga hu
Wọn wa di ẹ
Assignment
Wọn wa di ẹ
Assignment
Ó wọ kini yẹn
Assignment
Wọn wa di ẹ
Assignment

SHARE THIS

Author:

0 comments: